Skip to main content

Ojúewé Àkọ́kọ́ Ètò ìtọ́sọ́nàWAPWikispeciesWikinewsWikimedia CommonsMeta-Wiki

Wikipedia pages protected against vandalismWikipedia protected pages without expiry


ÌlànàÀwọn Ìbéèrè Wíwọ́pọ̀ÀgbàjọÀwọn ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ WikipediaỌrẹIbi Ìṣojú (Embassy)ÌbápàdéNew York Cityìtẹ̀síwájú...SofiaBulgariaÀìṣojúṣájúÌlànà àyọkà kíkọẸ̀tọ́àwòkọÌwà títọ́Ìṣeéyẹ̀wòÌlànà fún kíkọ lẹ́tà YorùbáKíni Wikipedia jẹ́?Àtúnṣe ojúewéÀfikún àwòránÌkópaTutorialÀpótí ìdánwòÀwọn ojúewé tuntunÀwọn àyọkà ọ̀wọ́nÀwọn ojúewé fún ìyílédèdàÀwọn àyọkà fún àtúnṣeÌṣọrẹAbẹ́ igiÀwọn oníṣe WikipediaÀwọn alámùójútóWikimediaSoftwareÀwọn statístíkìWikipediaLítíréṣọ̀Eré-ìdárayáFílmùOrinTíátàÌṣeròyìnTẹlifísànRédíòIṣẹ́ẹ̀rọInternetÀfigbébánisọ̀rọ̀Kọ̀mpútàẸbíFàájìÒfinỌ̀rọ̀-òkòwòÌnáwóÌṣèlúỌ̀rọ̀-àwùjọÈnìyànẸ̀kọ́ÌmòyeÌtòràwọ̀ÒfurufúỌ̀gbìnSáyẹ́nsì kọ̀mpútàFísíksìÌwòsànÀdánidáKẹ́místrìBàíọ́lọ́jìÁljẹ́bràÌtúwòÌṣíròÌṣedọ́gbaJẹ́ọ́mẹ́trìNọ́mbàTẹ̀ọ́rẹ́mùỌgbọ́nAyéAdágúnOrílẹ̀-èdèÒkunOrílẹ̀ÌlúÁfríkàÁsíàEuropeGúúsù Amẹ́ríkàÀríwá Amẹ́ríkàOgunOrílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀Ilẹ̀ọbalúayéỌ̀rọ̀-ayéijọ́unOlórí orílẹ̀-èdèOníṣọ̀nàÒṣeréOnímọ̀sáyẹ́nsìAmòyeOlóṣèlúOlùkọ̀wéOníṣòwòẸ̀sìn YorùbáÌmàleẸ̀sìn KrístìÌṣebúddhàÌṣehíndùÌmáralókunÌdárayáAmáralókunìtọ́jú ìleraÀrùnỌ̀rọ̀-àjàkálẹ̀àrùnDeutsch (jẹ́mánì)English (gẹ̀ẹ́sì)Français (faransé)Español (spánì)Italiano日本語 (japonês)Nederlands (neerlandês)Polski (polaco/polonês)Português (potogí)Русский (rọ́síà)العربية (árabe)Български (búlgaro)Català (catalão)한국어 (coreano)中文 (chinês)Dansk (dinamarquês)Slovencina (eslovaco)Slovenščina (esloveno)EsperantoSuomi (finlandês)עברית (hebraico)Magyar (húngaro)Bahasa Indonesia (indonésio)Lietuviu (lituano)Norsk (norueguês)فارسی (persa)Română (romeno)Српски / Srpski (sérvio)Svenska (sueco)Česká (tcheco/checo)Türkçe (turco)Українська (ucraniano)Tiếng Việt (vietnamita)Volapük (volapuque)Winaray












Ojúewé Àkọ́kọ́




Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́






Jump to navigation
Jump to search









Àdàkọ:ÀyọkàỌ̀sẹ̀ Àyọkà pàtàkì ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀



Àwòrán Ise-ona funfun Iboju Iyaoba Idia ilu Benin

Ẹ̀gbà ọrùn bí ìbòju tí Benin jẹ́ ẹ̀gbà ọrùn tí wọ́n gbẹ́ lére tí ó sì jẹ́ àwòrán akọni obìrin tí a mọ̀ si ìyá wa Olorì Idia ti ọ̀rundún mẹ́rìndínlógún ṣẹ́yìn. Ọmọ rẹ̀ Esigie tí ó jẹ́ ọba  ti Benin maa ń wọ́ èyí tí ó jọọ́ fún àwọn ọmọ ogun ẹ̀yìn ìya olorì. Ibojú yìyí tí ó jọrawọ méjì ní ó wà: Ìkan wà ní Ilé ọnà ti a mọ̀ sí British Museum ní ìlú London tí ìkejì sì wà ní ilé ọnà tí a mọ̀ sí Metropolitan Museum of Art in New York City.


Àwọn àpẹẹrẹ rẹ̀ lórí àkọ́lé kan náà wà ní Seattle Art Museum àti Linden Museum, tí ìkan ná sì wà ní ilé ibi tí wọ́n kò gba gbogboògbò láyè láti wọ̀, gbogbo rẹ̀ ní wọ́n kó nígbà ìwádí lọ sí ìlú Benin ti ọdún 1897.


Ìbojú yìí ti di àmì ìdánimọ̀ lóde òní ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríá̀ láti ìgbà ìpéjọpọ̀ kan tí a mọ̀ sí FESTAC 77 tí ó wáyé ní ọdún 1977.


Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó ní ìrísí èyí tí ó jọ Ìbojú Ìbílẹ̀ Aláwọ̀dúdú, kíní kékeré tí gúngùn rẹ̀ kò ju 24cm lọ kìí ṣé fún wíwọ̀ sójú, Ọba lè wọ̀ọ́ sọ́rùn (tí ó sì maa bá mu) tàbí bi "ìlẹ̀kẹ̀ ìbàdí " (èyí tí ó sì maa bá ayẹyẹ tí ó fẹ́ sẹe mu). Èyí tí ó wà ní ilé ọnà Met àti èyí tí ó wà ní ilé ọnà British fẹ́ jọ ara wọn, méjèèjì ni ó jẹ́ àwòràn Olorì Idia
wearing ìlẹ̀kẹ̀ lórí, ìlẹ̀kẹ̀ lọ́rùn, ọgbẹ́ níwájú orí àti gbígbẹ́  èyí tí ó fàyè ọ̀nà méjì tí wọ́n lè fi ẹ̀gbà kọ́.


Lóde òní àwọn ènìyàn m,aa ń gbé onírú irú àworan tí ó jọ́ọ níbi ayẹyẹ láti lé ẹbọra búrúkú, ṣùgbọ́n ní bí ọrundún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn, wọ́n lè maa lòó fún ayẹyẹ ìya ọba. Ó dàbí wípé ní bí ìbẹ̀rẹ̀ ọrúndún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn ni wọ́n gbẹ́ àwọn ibojú méjèèjì, bóya ní ọdún 1520, nígbà tí Olorì Idia, ìyá ọba Oba Esigie, jẹ́ olùdájọ́ ní ilé ẹjọ́ ti Benin.
(ìtẹ̀síwájú...)






Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 15 Oṣù Kẹrin Ní ọjọ́ òní...



Ọjọ́ 15 Oṣù Kẹrin:



  • 1896 – Closing ceremony of the Games of the I Olympiad in Athens, Greece.


  • 1912 – The British passenger liner, the RMS Titanic, sinks in the North Atlantic at 2:20 a.m., two and a half hours after hitting an iceberg. 1,517 people are killed.


  • 1947 – Jackie Robinson debuts for the Brooklyn Dodgers, breaking baseball's color line.


  • 1989 – Tiananmen Square protests of 1989 begin in the People's Republic of China.

Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...



  • 1452 – Leonardo da Vinci, Italian Renaissance polymath (d. 1519)


  • 1889 – A. Philip Randolph, American activist (d. 1979)


  • 1894 – Nikita Khrushchev, Premier of the Soviet Union (d. 1971)

Àwọn aláìsí lóòní...



  • 1865 – Abraham Lincoln, 16th President of the United States (b. 1809)


  • 1980 – Jean-Paul Sartre, French philosopher and writer, Nobel laureate (b. 1905)


  • 1998 – Pol Pot, Cambodian dictator (b. 1925)

Ọjọ́ míràn: 13 • 14 • 15 • 16 • 17 | ìyókù...








Nuvola apps filetypes.svgṢé ẹ mọ̀ pé...


  • ... pé Òdo pátápátá dọ́gba mọ́ -273.15 °C?

  • ... pé àwọn electron jẹ́ wíwárí látọwọ́ J.J. Thomson ní 1897?

  • ... pé Gáláksì Andromẹ́dà ní iye ìràwọ̀ tó pọ̀ ju ẹgbẹẹgbẹ̀rúnlẹ́ta lọ?







Èbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyí/Kókó orí Ìròyìn ìwòyí



Higgs, Peter (1929)3.jpg


  • Nelson Mandela ṣe aláìsí ní Johannesburg, Gúúsù Áfríkà.


  • Nobel fún Àlàfíà lọ sí Àgbájọ fún Ìdènà àwọn Ohun Ìjagun Ògùn Olóró.


  • Nobel fún Litiréṣọ̀ lọ sí Alice Munro.


  • Nobel fún Kẹ́místrì lọ sí Martin Karplus, Michael Levitt àti Arieh Warshel.


  • Nobel fún Físíksì lọ sí François Englert àti Peter Higgs (fọ́tò).


  • Nobel fún Ìwòsàn lọ sí James Rothman, Randy Schekman àti Thomas C. Südhof.






Ẹ tún wo ÌròyìnWiki ní èdè Gẹ̀ẹ́sì




Nuvola filesystems camera.pngÀwòrán ọjọ́ òní




AlexanderNevskyCathedral-Sofia-6.jpg

Ilé-Ìsìn St. Alexander Nevsky ní Sofia, Bulgaria.








Wikimedia logo family complete.svg Àwọn Iṣẹ́-ọwọ́ Míràn



Wikimedia Foundation ni ó gba àlejò Wikipedia, egbe-alasepo ti ki se fun ere ti o tun se alejo opo awon ise-owo miran:












Wikiàyásọ

Wikiàyásọ
Àkójọ àwọn àmúsọ

Wikiatúmọ̀èdè

Wikiatúmọ̀èdè
Atúmọ̀èdè orísirísi èdè

Wikispecies

Wikispecies
Àkójọ àwọn irú ẹ̀dá

Wikiìròyìn

Wikinews
Ìròyìn ọ́fẹ̀










Wikisource

Wikisource
Àwọn àkọsíìwé ọ̀fẹ́

Commons

Wikimedia Commons
Àwòrán, ìró àti fídéò

Wikifásítì

Wikifásítì
Èlò ìkọ́ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́

Wikiìwé

Wikiìwé
Ìwéẹ̀kọ́ àti ìwéàwòṣe ọ̀fẹ́





Meta-Wiki

Meta-Wiki
Ibi àkóso ìṣẹ́-ọwọ́ Wikimedia

Wikidata

Wikidata
Ìbùdó ìmò ọ̀fẹ́




Àkíyèsí! — Àìṣojúṣájú · Ìlànà àyọkà kíkọ · Ẹ̀tọ́àwòkọ · Ìwà títọ́ · Ìṣeéyẹ̀wò · Ìlànà fún kíkọ lẹ́tà Yorùbá



Kíkọ àyọkà — Kíni Wikipedia jẹ́? · Àtúnṣe ojúewé · Àfikún àwòrán · Ìkópa · Tutorial · Àpótí ìdánwò



Ìrànwọ́ Wikipedia — Àwọn ojúewé tuntun · Àwọn àyọkà ọ̀wọ́n · Àwọn ojúewé fún ìyílédèdà · Àwọn àyọkà fún àtúnṣe · Ìṣọrẹ



Nípa Wikipédia — Abẹ́ igi · FAQ · Àwọn oníṣe Wikipedia · Àwọn alámùójútó · Wikimedia · Software · Àwọn statístíkì



Orúkọàyè — Wikipedia







Àdàkọ:GbogboẸ̀ka Àwọn èbúté àti ẹ̀ka àyọkà


























Àṣà

Lítíréṣọ̀ • Eré-ìdárayá • Fílmù • Orin • Tíátà • Ìṣeròyìn • Tẹlifísàn • Rédíò





Tẹknọ́lọ́jì

Iṣẹ́ẹ̀rọ • Internet • Àfigbébánisọ̀rọ̀ • Kọ̀mpútà





Àwùjọ

Ẹbí • Fàájì • Òfin • Ọ̀rọ̀-òkòwò • Ìnáwó • Ìṣèlú • Ọ̀rọ̀-àwùjọ • Ènìyàn • Ẹ̀kọ́ • Ìmòye





Sáyẹ́nsì

Ìtòràwọ̀ • Òfurufú • Ọ̀gbìn • Sáyẹ́nsì kọ̀mpútà • Físíksì • Ìwòsàn • Àdánidá • Kẹ́místrì • Bàíọ́lọ́jì





Mathimátíkì

Áljẹ́brà • Ìtúwò • Ìṣírò • Ìṣedọ́gba • Jẹ́ọ́mẹ́trì • Nọ́mbà • Tẹ̀ọ́rẹ́mù • Ọgbọ́n





Jẹ́ọ́gráfì

Ayé • Adágún • Orílẹ̀-èdè • Òkun • Orílẹ̀ • Ìlú • Áfríkà • Ásíà • Europe • Gúúsù Amẹ́ríkà • Àríwá Amẹ́ríkà





Ìtàn

Ogun • Orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀ • Ilẹ̀ọbalúayé • Ọ̀rọ̀-ayéijọ́un





Ìgbésíayé

Olórí orílẹ̀-èdè • Oníṣọ̀nà • Òṣeré • Onímọ̀sáyẹ́nsì • Amòye • Olóṣèlú • Olùkọ̀wé • Oníṣòwò





Ẹ̀sìn àti ìgbàgbọ́

Ẹ̀sìn Yorùbá • Ìmàle • Ẹ̀sìn Krístì • Ìṣebúddhà • Ìṣehíndù





Ìlera

Ìmáralókun • Ìdárayá • Amáralókun • ìtọ́jú ìlera • Àrùn • Ọ̀rọ̀-àjàkálẹ̀àrùn






Àkọ́jọ kíkúnrẹ́rẹ́ · Ibiàkóso àwọn èdè Wikipedia · Ìdásílẹ̀ èdè Wikipedia tuntun









Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Ojúewé_Àkọ́kọ́&oldid=523403"










Ètò ìtọ́sọ́nà



























(window.RLQ=window.RLQ||[]).push(function()mw.config.set("wgPageParseReport":"limitreport":"cputime":"0.188","walltime":"0.271","ppvisitednodes":"value":453,"limit":1000000,"ppgeneratednodes":"value":0,"limit":1500000,"postexpandincludesize":"value":31295,"limit":2097152,"templateargumentsize":"value":2098,"limit":2097152,"expansiondepth":"value":12,"limit":40,"expensivefunctioncount":"value":1,"limit":500,"unstrip-depth":"value":0,"limit":20,"unstrip-size":"value":1,"limit":5000000,"entityaccesscount":"value":0,"limit":400,"timingprofile":["100.00% 80.640 1 -total"," 25.21% 20.329 1 Àdàkọ:Pp-vandalism"," 20.58% 16.597 1 Àdàkọ:Pp-meta"," 16.21% 13.068 1 Àdàkọ:ÀwòránỌjọ́Òní"," 12.85% 10.359 1 Àdàkọ:Aworan"," 10.36% 8.358 1 Wikipedia:Ojúewé_Àkọ́kọ́/Àyọkà_Ọ̀sẹ̀/Ọ̀ṣẹ̀_yí"," 9.19% 7.409 1 Wikipedia:Àwọn_Ìṣẹ̀lẹ̀_Bíi_Ọjọ́_Òní/Ọjọ́_15_Oṣù_Kẹrin"," 7.64% 6.160 1 Wikipedia:Ṣé_ẹ_mọ̀_pé..."," 6.98% 5.626 1 Àdàkọ:ÀyọkàỌ̀sẹ̀"," 5.98% 4.826 2 Àdàkọ:Multiview"],"cachereport":"origin":"mw1272","timestamp":"20190415184112","ttl":3600,"transientcontent":true);mw.config.set("wgBackendResponseTime":146,"wgHostname":"mw1265"););

Popular posts from this blog

Identifying “long and narrow” polygons in with PostGISlength and width of polygonWhy postgis st_overlaps reports Qgis' “avoid intersections” generated polygon as overlapping with others?Adjusting polygons to boundary and filling holesDrawing polygons with fixed area?How to remove spikes in Polygons with PostGISDeleting sliver polygons after difference operation in QGIS?Snapping boundaries in PostGISSplit polygon into parts adding attributes based on underlying polygon in QGISSplitting overlap between polygons and assign to nearest polygon using PostGIS?Expanding polygons and clipping at midpoint?Removing Intersection of Buffers in Same Layers

Masuk log Menu navigasi

อาณาจักร (ชีววิทยา) ดูเพิ่ม อ้างอิง รายการเลือกการนำทาง10.1086/39456810.5962/bhl.title.447410.1126/science.163.3863.150576276010.1007/BF01796092408502"Phylogenetic structure of the prokaryotic domain: the primary kingdoms"10.1073/pnas.74.11.5088432104270744"Towards a natural system of organisms: proposal for the domains Archaea, Bacteria, and Eucarya"1990PNAS...87.4576W10.1073/pnas.87.12.4576541592112744PubMedJump the queueexpand by handPubMedJump the queueexpand by handPubMedJump the queueexpand by hand"A revised six-kingdom system of life"10.1111/j.1469-185X.1998.tb00030.x9809012"Only six kingdoms of life"10.1098/rspb.2004.2705169172415306349"Kingdoms Protozoa and Chromista and the eozoan root of the eukaryotic tree"10.1098/rsbl.2009.0948288006020031978เพิ่มข้อมูล